EUVIMEDEUVIMED entdecken
Crossref

Ìlo Òògùn apa kòkòro ara, Ràlẹ̀rálẹ̀, Aṣàtakò àti Ìṣàkósọ Ẹ̀ka Ohun-jíjẹ àti Iṣé Àgbẹ̀, Tanzania

ST Communications

AfricArXiv · 24.07.2023

DOI: 10.21428/3b2160cd.a858ade1 ↗

Kurz gefasst

Fachartikel in der Zeitschrift AfricArXiv, online erschienen am 24.07.2023. Verfasst von ST Communications.

AbstractBibliografische AngabenZitierenVerwandte Studien

Abstract (Originalsprache)

Gbogbo àrùn ni ó ṣe é wò níwọǹ ìgbà tí àwọn kòkòrò-àìfojúrí tí ń fa àrùn ò bá ní agbára tó òògùn apa kòkòro ara.Iṣọwó tí ipá àwọn òògùn apa kòkòro ara ṣe ń díkùn ti ń di ewu fún ètò ìlèrà ágbàáyé èyí sì jẹ́ ewu ńlá tí ó lè mú ìfàsẹýìn bá òògùn apa kòkòro ara fún ìkápá àrùn.Bí bíbéèrè fún àwọn oúnjẹ tí wọń ṣẹdá láti ara ẹranko ṣe ń pọ̀ si, pàápàá jùlọ ẹyin, ẹran, àti mílíìkì èyí ló ṣokùnfa ètò ìṣelọṕọ̀ àwọn oúnjẹ yìí fún títà, èyí sì lè jẹ́ kí àpọjù àti àṣìlò àwọn ohun òògùn apa kòkòro ara.Òògùn apa kòkòro ara, tí ó wà lọẃọ́ àwọn àgbẹ̀ àti àwọn lamóòjútó ẹran ọsìn, tí wọń ń lò ó láìní ẹkọ́ ìwé, lè di àṣìlò àti ṣíṣe sí àìgbọŕàn àsìkò dídínkù rẹ.A ṣe ìwádìí yìí láti mọ àwọn òfin àti ìṣàkóso àwọn òògùn apa kòkòro ara, láti fí ọǹà àti òṣùwọǹ ìlò wọn múlẹ, ṣàyẹẁò àwọn ràlẹrálẹ̀ òògùn apa kòkòro ara àti aṣàtakò tó wà nínú oúnjẹ ohun ọsìn àti ètò aṣàróbọ̀ ohun ọgbìn, àti láti ṣe àkàwé ìwádìí yìí sí àwọn ọǹà ìgbà gbógun ti ìfarahàn aṣàtakò òògùn apa kòkòro ara ní Tanzania.Oríṣi ọǹà ìgbà ṣe nǹkan (àtúnyẹẁò abẹĺé, ìwádìí, ìfọrọ-wáni-lẹńuwò lọĺọḱan-ọjọkan) ni wọń ṣàmúò.Àbẹẁò àwọn ilé-iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì sí ìwádìí.Ìjábọ̀ wà pé ìtakò tó lágbára sí pẹnsilíí G, kilorafẹńíkọ, sẹtẹtomisíí, ọsitẹtirasaikílíìnì, pàápàá fún jùlọ fún Actinobacter pyogenes, àti oríṣiríṣi àtọsí láti ara màálù tí wọn fún wàrà pẹlú àrùn ọmú nínú àwọn eniyan.Wọń rí ohun tí ó jọmọ́ àrùn yìí ní ilé adìyẹ níbi tí àwọn eyin àti ẹran ti kó àrùn kọĺì (E.coli) tí ó tako àwọn òògùn ìpa-kòkòkò-batéríà amọsilíì + kilafulanáàtì, sulphamethoxazole àti neomycin.Ìṣọwọ́ jẹyọ àwọn òògùn atako òògùn apa kòkòro ara bí I E.coli, klebsiella pneumonia, staphylococcus aureus àti Salmonella pọjù bẹẹ̀ náà ni wọń jẹyọ nínú àwọn ẹran-an jẹ.Ìjábọ̀ wà fún ìṣọwọ́ jẹyọ àrun methicillin-resistant staphylococcus aureus (MRSA) àti extended-spectrum beta-lactamase(ESBL) láàárín àwọn ẹka ohun ọsìn ní Tanzania.

Zitieren

APA

Communications, S. (2023). Ìlo Òògùn apa kòkòro ara, Ràlẹ̀rálẹ̀, Aṣàtakò àti Ìṣàkósọ Ẹ̀ka Ohun-jíjẹ àti Iṣé Àgbẹ̀, Tanzania. AfricArXiv. https://doi.org/10.21428/3b2160cd.a858ade1

Vancouver

Communications S. Ìlo Òògùn apa kòkòro ara, Ràlẹ̀rálẹ̀, Aṣàtakò àti Ìṣàkósọ Ẹ̀ka Ohun-jíjẹ àti Iṣé Àgbẹ̀, Tanzania. AfricArXiv. 2023. doi:10.21428/3b2160cd.a858ade1

BibTeX
@article{Communications2023,
  author = {Communications, ST},
  title = {Ìlo Òògùn apa kòkòro ara, Ràlẹ̀rálẹ̀, Aṣàtakò àti Ìṣàkósọ Ẹ̀ka Ohun-jíjẹ àti Iṣé Àgbẹ̀, Tanzania},
  journal = {AfricArXiv},
  year = {2023},
  doi = {10.21428/3b2160cd.a858ade1}
}
Kostenlos starten →